Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tún sọ fún mi pé, “Kéde gbogbo ọ̀rọ̀ yìí ní àwọn ìlú Juda ati ní àwọn òpópó Jerusalẹmu, pé kí wọn fetí sí ọ̀rọ̀ majẹmu yìí, kí wọ́n sì ṣe bí ó ti wí.

Ka pipe ipin Jeremaya 11

Wo Jeremaya 11:6 ni o tọ