Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá ṣe bẹ́ẹ̀, n óo mú ẹ̀jẹ́ tí mo jẹ́ fún àwọn baba ńlá yín ṣẹ, pé n óo fún wọn ní ilẹ̀ tí ó kún fún wàrà ati oyin,’ bí ó ti rí ní òní.”Mo bá dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, OLUWA.”

Ka pipe ipin Jeremaya 11

Wo Jeremaya 11:5 ni o tọ