Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 11:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun ní òun óo jẹ wọ́n níyà; àwọn ọdọmọkunrin wọn yóo kú lójú ogun, ìyàn ni yóo sì pa àwọn ọmọkunrin ati ọmọbinrin wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 11

Wo Jeremaya 11:22 ni o tọ