Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àgọ́ mi ti wó, gbogbo okùn rẹ̀ sì ti já.Àwọn ọmọ mi ti fi mí sílẹ̀, wọn kò sì sí mọ́.Kò sí ẹni tí yóo máa bá mi pa àgọ́ mọ́,bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹni tí yóo máa bá mi ta aṣọ àgọ́ mi.

Ka pipe ipin Jeremaya 10

Wo Jeremaya 10:20 ni o tọ