Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà ayé Josaya, ọmọ Amoni, ọba Juda, ní ọdún kẹtala tí Josaya gun orí oyè ni OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 1

Wo Jeremaya 1:2 ni o tọ