Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 9:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí yóo jẹ́ àmì majẹmu tí mo ń bá ẹ̀yin ati gbogbo ẹ̀dá alààyè dá, tí yóo sì wà fún atọmọdọmọ yín ní ọjọ́ iwájú nìyí:

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 9

Wo Jẹnẹsisi 9:12 ni o tọ