Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 5:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Lamẹki bí Noa, ó gbé ọdún marundinlẹgbẹta (595) láyé, ó sì bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 5

Wo Jẹnẹsisi 5:30 ni o tọ