Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 5:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àkọsílẹ̀ ìran Adamu nìyí: Nígbà tí Ọlọrun dá eniyan, ó dá wọn ní àwòrán ara rẹ̀.

2. Takọ-tabo ni ó dá wọn, ó súre fún wọn, ó sì sọ wọ́n ní eniyan.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 5