Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 49:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo máa so ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ mọ́ ìtàkùn àjàrà,yóo so àwọ́nsìn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ mọ́ ìtàkùn àjàrà dáradára,bẹ́ẹ̀ ni oje àjàrà ni yóo máa fi fọ ẹ̀wù rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 49

Wo Jẹnẹsisi 49:11 ni o tọ