Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 45:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí ó gbọ́ gbogbo ohun tí Josẹfu wí fún wọn, tí ó tún rí kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin tí Josẹfu fi ranṣẹ pé kí wọ́n fi gbé òun wá, ara rẹ̀ wálẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 45

Wo Jẹnẹsisi 45:27 ni o tọ