Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 44:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó dá wọn lóhùn, ó ní, “Kí á má rí i pé mo ṣe ohun tí ó jọ bẹ́ẹ̀. Ẹnìkan ṣoṣo tí wọ́n ká ife náà mọ́ lọ́wọ́ ni yóo di ẹrú mi, ní tiyín, ẹ máa pada tọ baba yín lọ ní alaafia.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:17 ni o tọ