Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 44:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Juda dá a lóhùn, ó ní, “Kí ni a rí tí a lè wí fún ọ, oluwa mi? Ọ̀rọ̀ wo ni ó lè dùn lẹ́nu wa? Ọṣẹ wo ni a lè fi wẹ̀, tí a fi lè mọ́? Ọlọrun ti rí ẹ̀bi àwa iranṣẹ rẹ. Wò ó, a di ẹrú rẹ, oluwa mi, ati àwa ati ẹni tí wọ́n bá ife náà lọ́wọ́ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 44

Wo Jẹnẹsisi 44:16 ni o tọ