Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá pe Kaini, ó bi í pé, “Níbo ni Abeli, àbúrò rẹ wà?” Ó dáhùn, ó ní, “N kò mọ̀. Ṣé èmi wá jẹ́ bí olùṣọ́ àbúrò mi ni?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 4

Wo Jẹnẹsisi 4:9 ni o tọ