Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 35:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò wọn. Jìnnìjìnnì láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun sì dà bo gbogbo àwọn ìlú tí ó wà ní àyíká wọn, wọn kò sì lépa àwọn ọmọ Jakọbu.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35

Wo Jẹnẹsisi 35:5 ni o tọ