Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí ọkunrin yóo ṣe fi baba ati ìyá rẹ̀ sílẹ̀, tí yóo sì faramọ́ aya rẹ̀, àwọn mejeeji yóo sì di ara kan ṣoṣo.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 2

Wo Jẹnẹsisi 2:24 ni o tọ