Ọkunrin náà bá wí pé,“Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rí ẹni tí ó dàbí mi,ẹni tí a mú jáde láti inú egungun ati ẹran ara mi;obinrin ni yóo máa jẹ́,nítorí pé láti ara ọkunrin ni a ti mú un jáde.”