Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 18:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún dáhùn pé “Jọ̀wọ́ dárí àfojúdi mi jì mí nítorí ọ̀rọ̀ mi, bí a bá rí ogún eniyan ńkọ́?” OLUWA tún dáhùn pé, “Nítorí ti ogún eniyan, n kò ní pa á run.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:31 ni o tọ