Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 18:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá tún wí pé, “OLUWA, jọ̀wọ́ má bínú sí mi, bí a bá rí ọgbọ̀n eniyan ńkọ́?” OLUWA dáhùn pé, “Bí mo bá rí ọgbọ̀n olódodo, n kò ní pa ìlú náà run.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:30 ni o tọ