Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọ̀sán gangan ọjọ́ kan, OLUWA fara han Abrahamu bí ó ti jókòó ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ rẹ̀, lẹ́bàá igi Oaku ti Mamure.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:1 ni o tọ