Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 16:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ó pe orúkọ OLUWA tí ó bá a sọ̀rọ̀ ní “Ìwọ ni Ọlọrun tí ń rí nǹkan.” Nítorí ó wí pé, “Ṣé nítòótọ́ ni mo rí Ọlọrun, tí mo sì tún wà láàyè?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 16

Wo Jẹnẹsisi 16:13 ni o tọ