Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Oníjàgídíjàgan ẹ̀dá ni yóo jẹ́, bíi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ inú igbó, yóo máa bá gbogbo eniyan jà, gbogbo eniyan yóo sì máa bá a jà, títa ni yóo sì takété sí àwọn ìbátan rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 16

Wo Jẹnẹsisi 16:12 ni o tọ