Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun súre fún wọn, ó ní, “Ẹ máa bímọ lémọ, kí ẹ sì máa pọ̀ sí i, kí ẹ kún gbogbo inú omi òkun, kí àwọn ẹyẹ náà sì máa pọ̀ sí i lórí ilẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:22 ni o tọ