Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá àwọn ẹranko ńláńlá inú omi ati oríṣìíríṣìí ẹ̀dá alààyè tí ń gbé inú omi, ati oríṣìíríṣìí ẹyẹ. Ọlọrun wò wọ́n, ó sì rí i pé wọ́n dára.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:21 ni o tọ