Bí orílẹ̀-èdè kan bá dẹ́ṣẹ̀,léraléra ni wọ́n ó máa jọba,ṣugbọn bí orílẹ̀-èdè kan bá ní àwọn eniyan tí wọn ní òye ati ìmọ̀,yóo wà fún ìgbà pípẹ́.