Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 28:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ń rìn pẹlu òtítọ́ inú yóo rí ìgbàlà,ṣugbọn ẹni tí ń rìn ségesège yóo ṣubú sinu kòtò.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 28

Wo Ìwé Òwe 28:18 ni o tọ