Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 25:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sàn kí á máa gbé kọ̀rọ̀ kan lókè àjà,ju pé kí eniyan máa bá oníjàngbọ̀n obinrin gbé ilé lọ.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 25

Wo Ìwé Òwe 25:24 ni o tọ