Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọ́gbọ́n rí ibi, ó farapamọ́,ṣugbọn òpè ń bá tirẹ̀ lọ láìbìkítà,ó sì kó sinu ìyọnu.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 22

Wo Ìwé Òwe 22:3 ni o tọ