Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Òwe 15:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ìdáhùn pẹ̀lẹ́ a máa mú kí ibinu rọlẹ̀,ṣugbọn ọ̀rọ̀ líle níí ru ibinu sókè.

2. Lẹ́nu ọlọ́gbọ́n ni ọ̀rọ̀ ìmọ̀ ti ń jáde,ṣugbọn òmùgọ̀ a máa sọ̀rọ̀ agọ̀.

3. Ojú OLUWA wà níbi gbogbo,ó ń ṣọ́ àwọn eniyan burúkú ati àwọn eniyan rere.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 15