Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo fi tọkàntọkàn pinnu láti ṣàkíyèsí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ nílé ayé, mo rí i pé ọpọlọpọ eniyan ní ń lo agbára wọn lórí àwọn ẹlòmíràn sí ìpalára ara wọn.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 8

Wo Ìwé Oníwàásù 8:9 ni o tọ