Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 8:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹni tí ó lágbára láti dá ẹ̀mí dúró, tabi láti yí ọjọ́ ikú pada, gbèsè ni ikú, kò sí ẹni tí kò ní san án; ìwà ibi àwọn tí ń ṣe ibi kò sì le gbà wọ́n sílẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 8

Wo Ìwé Oníwàásù 8:8 ni o tọ