Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí Ọlọrun fún ní ọrọ̀, ohun ìní ati iyì, tí ó ní ohun gbogbo tí ó fẹ́; sibẹsibẹ Ọlọrun kò jẹ́ kí ó gbádùn rẹ̀, ṣugbọn àjèjì ni ó ń gbádùn rẹ̀. Asán ni èyí, ìpọ́njú ńlá sì ni.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 6

Wo Ìwé Oníwàásù 6:2 ni o tọ