Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìwé Oníwàásù 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ni ó mọ ohun tí ó dára fún eniyan láàrin ìgbà kúkúrú, tí kò ní ìtumọ̀, tí ó níí gbé láyé, àkókò tí ó dàbí òjìji tí ó ń kọjá lọ. Ta ló mọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ láyé lẹ́yìn òun, lẹ́yìn tí ó bá ti kú tán?

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 6

Wo Ìwé Oníwàásù 6:12 ni o tọ