Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 9:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá mi lóhùn, ó ní: “Ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ilé Israẹli ati ti Juda pọ̀jù. Ilẹ̀ náà kún fún ìpànìyàn, ìlú yìí sì kún fún ìwà àìṣẹ̀tọ́. Wọ́n ń wí pé, ‘OLUWA ti kọ ilẹ̀ yìí sílẹ̀, kò sì rí ohun tí ń ṣẹlẹ̀ ninu rẹ̀.’

Ka pipe ipin Isikiẹli 9

Wo Isikiẹli 9:9 ni o tọ