Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní mójú fo ọ̀rọ̀ wọn, n kò sì ní ṣàánú wọn. N óo da ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ wọn lé wọn lórí.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 9

Wo Isikiẹli 9:10 ni o tọ