Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 48:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́gbẹ̀ẹ́ agbègbè Gadi ní ìhà gúsù, ààlà ilẹ̀ náà yóo lọ láti Tamari títí dé ibi àwọn odò Meriba Kadeṣi, títí dé àwọn odò Ijipti, tí ó fi lọ dé Òkun Ńlá.

Ka pipe ipin Isikiẹli 48

Wo Isikiẹli 48:28 ni o tọ