Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 46:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní igun mẹrẹẹrin ni àwọn gbọ̀ngàn kéékèèké yìí wà. Ó gùn ní ogoji igbọnwọ (mita 20), ó sì fẹ̀ ní ọgbọ̀n igbọnwọ (mita 15) àwọn mẹrẹẹrin sì rí bákan náà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 46

Wo Isikiẹli 46:22 ni o tọ