Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 46:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá mú mi wá sí ibi gbọ̀ngàn tí ó wà ní ìta, ó mú mi yíká gbogbo igun mẹrẹẹrin gbọ̀ngàn náà, gbọ̀ngàn kéékèèké kọ̀ọ̀kan sì wà ní igun kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Isikiẹli 46

Wo Isikiẹli 46:21 ni o tọ