Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 46:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá mú mi gba ọ̀nà tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ ìlẹ̀kùn, ó bá mú mi lọ sí ibi àwọn yàrá tí ó wà ní apá àríwá ibi mímọ́ náà, tí ó jẹ́ ti àwọn alufaa, mo sì rí ibìkan níbẹ̀ tí ó wà ní ìpẹ̀kun ní apá ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 46

Wo Isikiẹli 46:19 ni o tọ