Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 46:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba kò gbọdọ̀ gbà ninu ilẹ̀ àwọn ará ìlú láti ni wọ́n lára; ninu ilẹ̀ tirẹ̀ ni kí ó ti pín ogún fún àwọn ọmọ rẹ̀. Kí ẹnikẹ́ni má baà gba ilẹ̀ ọ̀kankan ninu àwọn eniyan mi kúrò lọ́wọ́ wọn.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 46

Wo Isikiẹli 46:18 ni o tọ