Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 44:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Wọn kò gbọdọ̀ sọ ara wọn di aláìmọ́ nípa sísúnmọ́ òkú, ṣugbọn wọ́n lè sọ ara wọn di aláìmọ́ bí ó bá jẹ́ pé òkú náà jẹ́ ti baba wọn tabi ìyá wọn tabi ti ọmọ wọn lọkunrin ati lobinrin tabi ti arakunrin wọn tí kò tíì gbeyawo tabi arabinrin wọn tí kò tíì wọ ilé ọkọ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 44

Wo Isikiẹli 44:25 ni o tọ