Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 35:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ ọ́ di ahoro títí lae, ẹnikẹ́ni kò sì ní gbé inú àwọn ìlú rẹ mọ́. O óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Isikiẹli 35

Wo Isikiẹli 35:9 ni o tọ