Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 35:8 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo da òkú sí orí àwọn òkè ńláńlá rẹ, yóo kún. Bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn òkè kéékèèké rẹ, ati gbogbo àwọn àfonífojì rẹ, ati gbogbo ipa odò rẹ. Òkú àwọn tí a fi idà pa ni yóo kúnbẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 35

Wo Isikiẹli 35:8 ni o tọ