Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 31:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Igi kedari tí ó wà ninu ọgbà Ọlọrun kò lè farawé e.Bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀ka igi firi kò sì tó ẹ̀ka rẹ̀.Ẹ̀ka igi kankan kò dàbí ẹ̀ka rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni kò sí igikígi ninu ọgbà Ọlọrun tí ó lẹ́wà bíi rẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 31

Wo Isikiẹli 31:8 ni o tọ