Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 30:24 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún ọba Babiloni lágbára, n óo sì fi idà mi lé e lọ́wọ́; ṣugbọn n óo ṣẹ́ Farao lápá; yóo máa kérora níwájú rẹ̀ bí ẹni tí a ṣá lọ́gbẹ́ tí ó ń kú lọ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 30

Wo Isikiẹli 30:24 ni o tọ