Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 29:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọn ń gbé Ijipti yóo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA. “Nítorí pé ẹ fi ara yín ṣe ọ̀pá tí àwọn ọmọ Israẹli gbára lé; ṣugbọn ọ̀pá tí kò gbani dúró ni yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 29

Wo Isikiẹli 29:6 ni o tọ