Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 29:5 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo gbé ọ jù sinu aṣálẹ̀, ìwọ ati gbogbo ẹja inú odò Naili rẹ. Ẹ ó bọ́ lulẹ̀ ninu pápá tí ó tẹ́jú. Ẹnìkan kò sì ní kó òkú yín jọ, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní sin yín. Mo ti fi yín ṣe oúnjẹ fún àwọn ẹranko ati àwọn ẹyẹ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 29

Wo Isikiẹli 29:5 ni o tọ