Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 28:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí n óo fi àjàkálẹ̀ àrùn bá ọ jà n óo sì jẹ́ kí àgbàrá ẹ̀jẹ̀ máa ṣàn ní ìgboro rẹ. Àwọn tí wọ́n yí ọ ká yóo gbógun tì ọ́, wọn óo sì fi idà pa ọpọlọpọ eniyan ninu rẹ,’ nígbà náà o óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 28

Wo Isikiẹli 28:23 ni o tọ