Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 28:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, ‘Wò ó, mo lòdì sí ọ, ìwọ Sidoni. N óo sì fi ògo mi hàn láàrin rẹ. Wọn óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA nígbà tí mo bá ṣe ìdájọ́ fún àwọn tí ń gbé inú rẹ; tí mo sì fi ìwà mímọ́ mi hàn wọ́n.

Ka pipe ipin Isikiẹli 28

Wo Isikiẹli 28:22 ni o tọ