Àwọn ará Sidoni ati Arifadi ni atukọ̀ rẹ.Àwọn ọlọ́gbọ́n láti ilẹ̀ Ṣemeri wà lọ́dọ̀ rẹ,àwọn ni wọ́n ń darí ọkọ̀ ojú omi rẹ.