Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 26:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo fi idà pa àwọn ará ìlú kéékèèké tí ó wà ní agbègbè tí ó yí ọ ká. Wọn óo mọ òkítì sí ara odi rẹ, wọn yóo ru erùpẹ̀ jọ, wọn óo fi la ọ̀nà lẹ́yìn odi rẹ, wọn óo sì fi asà borí nígbà tí wọ́n bá ń gun orí odi rẹ bọ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 26

Wo Isikiẹli 26:8 ni o tọ